Home Orisirisi AARE ONA KAKANFO: Gani Adams setan lati wo ipebi
Orisirisi - January 7, 2018

AARE ONA KAKANFO: Gani Adams setan lati wo ipebi

Bi o ti ku ojo die ki Alaafin ti Oyo, Oba Lamidi Adeyemi, gbe opa ase le Aare Gani Adams lowo gege bi Aare Ona Kakanfo Yoruba eleekeedogun, Aare egbe OPC tele naa yoo wo Ipebi lati ojo Alaaruba.
Ninu Ipebi yii ni won yoo ti se eto pataki ati etutu to ye ki nnkan le dan moran lasiko tie.
Aare Gani Adams ko ni jade si ita titi di ojo Satide ti yoo gba opa ase naa ni ilu Oyo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Tinubu kí wọn nílé Akala l’Ogbomọṣọ, ò tún sàbẹ̀wò sí Gómìnà Mákindé

Tinubu kí wọn nílé Akala l’Ogbomọṣọ, ò tún sàbẹ̀wò sí Gómìnà Mákindé Ọrẹ Òtítọ́jù Nítorí à…