Home Èfè ati Àwàdà Ojú máa ti owó ní 2019 – Fela Durotoye
Èfè ati Àwàdà - January 3, 2018

Ojú máa ti owó ní 2019 – Fela Durotoye

Odu ni Adetokunbo Olufela Durotoye ni orileede yii ati ni oke okun, sugbon gbogbo eniyan moo si Fela Durotoye. O je ogunna gbongbo ti oro da lenu re daadaa. O si maa n se idanilekoo lorisiirisii fun awon elegbe-jegbe ni ile yii ati ni oke okun.
Ojise Olorun ni Fela Durotoye, o si maa n soro bi emi Olorun ba se fi han. O ni oju maa ti owo ninu idibo odun 2019 to n bo. O ni oju awon omo Naijiria ti la. Iya ti po ju ni orileede yii.
O ni iyalenu nla-nla lo si maa je fun awon to lowo ati oruko ni ilu yiii ni igba ti won ba ja kule nibi idibo odun 2019 naa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Tinubu kí wọn nílé Akala l’Ogbomọṣọ, ò tún sàbẹ̀wò sí Gómìnà Mákindé

Tinubu kí wọn nílé Akala l’Ogbomọṣọ, ò tún sàbẹ̀wò sí Gómìnà Mákindé Ọrẹ Òtítọ́jù Nítorí à…