Home Orisirisi Obinrin yoo seku pa awon oloselu nla kan lodun yii – Tunde Bakare
Orisirisi - January 2, 2018

Obinrin yoo seku pa awon oloselu nla kan lodun yii – Tunde Bakare

Oludasile ijo Latter Rain Assembly, Pastor Tunde Bakare, ti jise ijaya fun awon oloselu Nijiria.
O ni bi awon kan fo ti won deye, won yoo ku iku latipase obinrin lodun yii.
Eyi wa lara asotele to so nidaji Monday.
Bakare ni lodun 1998, Olorun fihan oun pe Ogagun Sanni Abacha yoo ku nipase awon obinrin meji, eyi to si waye bee.
Bakan naa, Bakare ni Olorun ti so fun oun ki oun dije fun ipo Aare Naijiria.
O ni sugbon Olorun ko tii so pe ki oun tesiwaju bayii.
Bi Bakare ba dije ni 2019, a je pe yoo ba Aare Muhammadu figa gbaga, leyin ti won jo dije papo labe asia egbe CPC ni nnkan bii odun marun-un seyin.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Tinubu kí wọn nílé Akala l’Ogbomọṣọ, ò tún sàbẹ̀wò sí Gómìnà Mákindé

Tinubu kí wọn nílé Akala l’Ogbomọṣọ, ò tún sàbẹ̀wò sí Gómìnà Mákindé Ọrẹ Òtítọ́jù Nítorí à…