Home Orisirisi Allahu Akbar! Aramonda sele nile MC Oluomo
Orisirisi - January 2, 2018

Allahu Akbar! Aramonda sele nile MC Oluomo

Oga Agba awon onimoto ni Eko, Alhaji Musiliu Ayinde Akinsanya, ti so pe isele iyanu kan se ni ile oun ni ojo Monday ojo kinni osu kinni odun 2018 yii.
O ni oun deede ri oruko ALLAH loju omi ti won fe fi nu ile (mopping) ni ile oun.
Eyi fa a ki MC Oluomo maa kigba ALLAH leralera, tori inu re dun pe onise iyanu ni Waidu loke.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ìjàǹbá ọkọ̀ ní Fìdíwọ́ gbẹ̀mí èèyàn mẹ́fà láàrin ọ̀sẹ̀ kan

Ìjàǹbá ọkọ̀ ní Fìdíwọ́ gbẹ̀mí èèyàn mẹ́fà láàrin ọ̀sẹ̀ kan Ọrẹ Òtítọ́jù À fi kí Ọlọ́run má…