Home Orisirisi Agbara ojo yoo da Naijiria laamu ni 2018 – Baba Adeboye
Orisirisi - January 2, 2018

Agbara ojo yoo da Naijiria laamu ni 2018 – Baba Adeboye

Awon omo Naijiria to ba n gbe leti odo ko gbodo sun asun-han-an-run lodun yii o. Idi ni pe Oludari Agba Lagbaaye fun ijo Redeemed Chrustian Church of God, Pastor E. A. Adeboye, ti so asotele to bani leru lori agbara ojo.
O so pe ajalu ina ko ni po ni Naijiria ni 2918, sugbon ajalu agbara ojo n bo lona.
Baba Adeboye wa so pe awon omo Naijiria yoo ri idagbasoke ati itusile, sugbon won gbodo kun fun adura gidi.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Tinubu kí wọn nílé Akala l’Ogbomọṣọ, ò tún sàbẹ̀wò sí Gómìnà Mákindé

Tinubu kí wọn nílé Akala l’Ogbomọṣọ, ò tún sàbẹ̀wò sí Gómìnà Mákindé Ọrẹ Òtítọ́jù Nítorí à…