Home Orisirisi Owo awon olopaa te Yusuf Lawal to fe jale nibi konsaati Davido
Orisirisi - December 31, 2017

Owo awon olopaa te Yusuf Lawal to fe jale nibi konsaati Davido

Owo awon olopaa ilu Eko ti ba arakunrin kan, Yusuf Lawal, ati awon emewa re ti won ni odaran ati ole paraku ni won.
Awon olopaa ti ilu Eko gba won mu lojo ti akorin omo Baba Olowo n se ere Pataki, iyen N30 billion Concert ni Eko Hotel.
Won ni awon karanbaani naa pete lati ja awon eniyan lole lasiko konsaati naa.
Oga Olopaa, iyen DPO ti baraaki Bar Beach, Ogbeni Olusegun Ajamolaya, lo kede oro yii.
Awon yoku ti won fura si ni Saheed Olasupo, to je omo odun 27 and Babatunde Balogun, 28, Augustine Ode, Owoyele Moses, 27; Adewola Akinyeli, 28 ati George Daniel, 27.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Tinubu kí wọn nílé Akala l’Ogbomọṣọ, ò tún sàbẹ̀wò sí Gómìnà Mákindé

Tinubu kí wọn nílé Akala l’Ogbomọṣọ, ò tún sàbẹ̀wò sí Gómìnà Mákindé Ọrẹ Òtítọ́jù Nítorí à…