Home iroyin Omisore digbo lu Aregbesola
iroyin - December 31, 2017

Omisore digbo lu Aregbesola


Igbakeji gomina ni Ipinle Osun tele, Senito Iyiola Omisore, ti soko oro si Gomina Rauf Aregbesola lori eto isuna (bojeeti) to sese gbe kale fun ipinle naa.
Omisore ni bojeeti ti odun 2018 naa, to din die ni tirilionu kan naira je otubante ti ko le se awon ara ilu lore.
Omisore so fun awon oniroyin pe gbese ise kongila ati owo osise ti ijoba Aregbe je sile ko le je ki iru bojeeti naa mu ere wa.
O wa ro awon eniyan Osun ki won gbagbe nipa ijoba APC.
Sugbon sa o, nigba ti Aregbesola n se agbekale bojeeti naa, o mu da awon eniyan loju pe o je eyi ti yoo mu idagbasoke nla wolu.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ìjàǹbá ọkọ̀ ní Fìdíwọ́ gbẹ̀mí èèyàn mẹ́fà láàrin ọ̀sẹ̀ kan

Ìjàǹbá ọkọ̀ ní Fìdíwọ́ gbẹ̀mí èèyàn mẹ́fà láàrin ọ̀sẹ̀ kan Ọrẹ Òtítọ́jù À fi kí Ọlọ́run má…