Home iroyin Ìjọba Libya tún sọ̀kò ọmọ Nàìjíríà 175 ráńsẹ sílé
iroyin - December 31, 2017

Ìjọba Libya tún sọ̀kò ọmọ Nàìjíríà 175 ráńsẹ sílé

Gbogbo akitiyan ijoba apapo Naijiria nipa iya ti o n je awon omo Naijiria ni orileede Libya nipa bi won se fi tipa-ti-ikuuku fi won ranse sile, ko tii tu irun kankan lara awon orileede naa.
Ana ode yii ni won tun soko awon omo Naijiria marundinlogosan-an (175)si orilede yii. Ninu awon ti won so loko sile naa la ti ri okunrin merinlelogorin (84), obinrin merinlelaadota (54) pelu omode metadinlogoji (37).
Nnkan ibanuje ni eleyii je nitori pe opo awon omo Naijiria yii ni won ti fi gbogbo ara won sise kara-kara ti won ko si je ki won mu nnkankan ninu ise oogun won yii.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Tinubu kí wọn nílé Akala l’Ogbomọṣọ, ò tún sàbẹ̀wò sí Gómìnà Mákindé

Tinubu kí wọn nílé Akala l’Ogbomọṣọ, ò tún sàbẹ̀wò sí Gómìnà Mákindé Ọrẹ Òtítọ́jù Nítorí à…