Home iroyin Àwọn ẹlẹ́wọ̀n gba ìdásílẹ̀
iroyin - December 31, 2017

Àwọn ẹlẹ́wọ̀n gba ìdásílẹ̀

“Ori yeye ni mogun, ti aise lo pọ”. Ọpọ awọn alaisẹ lo ti wa ni ewon ti idajo won ko waye fun bii odun kanrin kese. Awon kan ti lo ju iye odun to ye ki won lo lo lewon ti idajo won ba tete waye.
Eyi lo mu ki olori idajo ni orileede yii, Onidajo Abubakar Malami siju aanu wo awon elewon kan pe ki won lo se odun pelu awon ebi won, ki awon naa si ye rin ni awon ona ti ko mo, nitori pe Yoruba bo won ni”ti eniyan ko ba rin ni igberi iro, won o ki n paa moo”.
Lara awon ti won gba idasile naa la ti ri eni ti won ko mo awon eni ibi loru, a ri awon to ti lo odun mokanla ni ewon lai ti gba idajo, a ri awon olodun mewaa ati bee bee lo.
Lara awon nnkan to tun ran awon elewon to ri idasile yii lowo gege bi Abubakar Malami se salaye fun awon oniroyin ni akunju ti awon ogba ewon naa n kun. Awon ogba ewon bii ti Kuje, ti ko ye ko gba ju eniyan eedegbeta (500) lo ti awon eedegberin (700) wa nibe ati bee bee lo.
Elewon merindinlaadoje (126) ni o gba idasile lati maa lo ni alaafia ara.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Tinubu kí wọn nílé Akala l’Ogbomọṣọ, ò tún sàbẹ̀wò sí Gómìnà Mákindé

Tinubu kí wọn nílé Akala l’Ogbomọṣọ, ò tún sàbẹ̀wò sí Gómìnà Mákindé Ọrẹ Òtítọ́jù Nítorí à…