Home Orisirisi Tope Alabi se bii Malaika, oun naa sile tuntun ni 2017
Orisirisi - December 30, 2017

Tope Alabi se bii Malaika, oun naa sile tuntun ni 2017


Awon osere Yoruba meji Pataki kan ko ni gbagbe odun 2017 yii o.
Awon naa ni Tope Alabi ati Sule Alao Malaika.
Awon mejeeji si ile nla nla tuntun ti won sese ko si ipinle Eko.
Oloto ni t’oun oto; nigba ti Malaka ko tie si Lekki, Tope ati oko re to je maneja re ko tiwon si Fagba ni agbegbe Iju-Agege.
Adura IROYIN OWURO nip e ile a tura o, bee tiwa naa a de.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ìjàǹbá ọkọ̀ ní Fìdíwọ́ gbẹ̀mí èèyàn mẹ́fà láàrin ọ̀sẹ̀ kan

Ìjàǹbá ọkọ̀ ní Fìdíwọ́ gbẹ̀mí èèyàn mẹ́fà láàrin ọ̀sẹ̀ kan Ọrẹ Òtítọ́jù À fi kí Ọlọ́run má…