Home iroyin Ọmọ Buhari tó ní ìjàm̀bá sì wà ní ilé-ìwòsàn Abuja – Garba Sheu
iroyin - December 28, 2017

Ọmọ Buhari tó ní ìjàm̀bá sì wà ní ilé-ìwòsàn Abuja – Garba Sheu

Iroyin gbigbona yajo-yajo kan n gbee kiri ni owuro oni pe won ti sare gbe Yusuf Buhari to se ijamba lori alupupu “Power Bike” ni ale ojo Isegun lo si orileede Germany.
Garba Sheu to je onimoran pataki nipa iroyin si Aare lo n fi awon omo Naijiria lokan bale pe, ko si eni to gbe Yusuf lo si Germany. O ni ile-iwosan aladaani kan lo wa ni Abuja. O ni loooto lo fete be ti o si fi ori pa. Gbogbo itoju to peye lo ti n lo lowo lori re bayii.
Garba tun fi asiko naa jise Aare Buhari ati iyawo re Aisha bi won se n dupe lowo omo Naijiria nipa adura ati aajo won lori omo naa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Tinubu kí wọn nílé Akala l’Ogbomọṣọ, ò tún sàbẹ̀wò sí Gómìnà Mákindé

Tinubu kí wọn nílé Akala l’Ogbomọṣọ, ò tún sàbẹ̀wò sí Gómìnà Mákindé Ọrẹ Òtítọ́jù Nítorí à…