Home Orisirisi Yusuf omo Buhari se ijamba lori alupupu igbalode
Orisirisi - December 27, 2017

Yusuf omo Buhari se ijamba lori alupupu igbalode


Osibitu kan ni ilu Abuja ni okan lara awon omo Aare Muhammadu Buhari wa bayii lo, latari bi o se sese ninu ijamba alupupu igbalode ti awon oloyinbo n pe ni power bike.
A gbo pe arakunrin naa, Yusuf Buhari, dede subu lule nigba ti alupupu naa ya bara kuro loju ona.
Koda, Akowe Iroyin Buhari, Ogbeni Garba Sheu, ti fi idi okodoro oro naa mule.
Won ni ijamba naa le debi pe o fun un ni egbo nla lori, to si je pe o run un ni eegun ese.
Sugbon sa o, Sheu ni won ti se ise abe fun Yusuf, to si je pe Olorun ti gbakoso.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Tinubu kí wọn nílé Akala l’Ogbomọṣọ, ò tún sàbẹ̀wò sí Gómìnà Mákindé

Tinubu kí wọn nílé Akala l’Ogbomọṣọ, ò tún sàbẹ̀wò sí Gómìnà Mákindé Ọrẹ Òtítọ́jù Nítorí à…