Home iroyin Oró ejò pa akẹ́kọ̀ọ́bìnrin Chibok mẹ́tàlá
iroyin - December 27, 2017

Oró ejò pa akẹ́kọ̀ọ́bìnrin Chibok mẹ́tàlá

Ibanuje dori agba kodo ni owuro oni ni igba ti iroyin kan gbee pe gege bi awon ologun Naijiria se n fina mo awon afemisofo Boko Haram. Won ko raaye se’toju to peye mo fun awon to wa ni sakani won.
Orisiirisii nnkan buruku ni iroyin gbe pe o n se awon eniyan to wa ni ahamo awon eniyan buruku naa. Awon nnkan bii ebi, iba ati aisan miran lorisiirisii ti ko si itoju to peye kankan mo.
Gbogbo abiyamo lo ba awon obi awon odomodebinrin Chibok yii kedun ni igba ti iroyin gbee pe ejo tun bu metala ninu won je ti oro ejo naa si je ki won dagbere faye. Bee ni awon kan ti bere adura kikan-kikan pe Olorun ko ni je ki o ri bee.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Tinubu kí wọn nílé Akala l’Ogbomọṣọ, ò tún sàbẹ̀wò sí Gómìnà Mákindé

Tinubu kí wọn nílé Akala l’Ogbomọṣọ, ò tún sàbẹ̀wò sí Gómìnà Mákindé Ọrẹ Òtítọ́jù Nítorí à…