Home iroyin Gbogbo ọmọ Yorùbá ló yẹ kó gbárùkù ti Gani Adams – Gbenga Daniel
iroyin - December 27, 2017

Gbogbo ọmọ Yorùbá ló yẹ kó gbárùkù ti Gani Adams – Gbenga Daniel

Gomina tele ri ni ipinle Ogun, Oloye Gbenga Daniel lo n parowa yii si gbogbo omo ile Yoruba ni igba to n ba awon oniroyin soro ni ilu Sagamu ni ipinle Ogun.
Daniel ni gbogbo wa ni lati gbaruku ti Aare Ona kakanfo naa fun ilosiwaju asa ati ise ile Yoruba. O ni eyi naa si maa je ki a le di ara wa ni osusu owo. O ni ote maa n te gbogbo nnkan daadaa ri ni.
Gomina tele ri naa ni eya tabi ilu to ba fe tete ni ilosiwaju o ki n fi oselu tabi esin siwaju gbogbo nnkan. O ni a gbodo koko mu ara wa bii omo iya kan ki a si fi ohun sokan fun ilosiwaju eya ati ojo iwaju awon omo wa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

IPOB láwọn ò fẹ́ àbẹ̀wò Ààrẹ Buhari sí ìpínlẹ̀ Imo

IPOB láwọn ò fẹ́ àbẹ̀wò Ààrẹ Buhari sí ìpínlẹ̀ Imo Fẹ́mi Akínṣọlá Ọ̀fọ́n àn tọ̀ sí gbẹ̀gìr…