Home Orisirisi Yegede, Omotola ri fonu re to sonu
Orisirisi - December 25, 2017

Yegede, Omotola ri fonu re to sonu


Idunnu ti pada si okan gbajugbaja osere fiimu, Omotola Jalaade-Ekeinde, leyin ti awon kan ti won ji foonu olowo iyebiye re, iyen iPhone, da a pada.
Lasiko to n kopa nibi eto kan to waye ni Ipinle Eko ni foonu naa di await.
Eyin eyi ni osere naa ke gbajare pe ki eni ti foonu naa wa lowo re jowo nitori Olorun ko ba oun da a pada.
Bi o tile je pe a ko mo boya Omotola fun eni naa ni owo tabi ebun miran, o rojo adura le e lori.
O ni lagbara Olorun, gbogbo oun ti o ba n wa ni yoo to o lowo. O ni iyonu Olorun yoo maa ba a gbe, bee oun to ba to si i ko ni di ti elomiran.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Tinubu kí wọn nílé Akala l’Ogbomọṣọ, ò tún sàbẹ̀wò sí Gómìnà Mákindé

Tinubu kí wọn nílé Akala l’Ogbomọṣọ, ò tún sàbẹ̀wò sí Gómìnà Mákindé Ọrẹ Òtítọ́jù Nítorí à…