Home Orisirisi Tinubu ní kí ọmọ Nàìjíríà ti Buhari lẹ́yìn
Orisirisi - December 25, 2017

Tinubu ní kí ọmọ Nàìjíríà ti Buhari lẹ́yìn

Olori egbe oselu APC, Asiwaju Bola Tinubu lo n ki awon elesin kirisiteeni ku odun. O wa n fi asiko naa parowa si gbogbo omo Naijiria pe “agbajo owo la fi n soya, ajeje owo kan ko gberu dori”.
O ni Aare Buhari nikan ko da ilu yii gbe de ebute ogo. O ni gbogbo omo Naijiria, lai fi ti egbe, esin ati eya se ni a le jo gbe orileede yii de ebute ogo.
Tinubu ni paapaa julo nipa eto oro-aje, a ni lati sa gbogbo agbara wa lati ran ilu ati ara wa lowo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Tinubu kí wọn nílé Akala l’Ogbomọṣọ, ò tún sàbẹ̀wò sí Gómìnà Mákindé

Tinubu kí wọn nílé Akala l’Ogbomọṣọ, ò tún sàbẹ̀wò sí Gómìnà Mákindé Ọrẹ Òtítọ́jù Nítorí à…