Home Orisirisi Tuface soro ibinu lori owon epo
Orisirisi - December 24, 2017

Tuface soro ibinu lori owon epo

Akorin pataki, Tuface Idibia, ti gba ijoba Buhari nimoran pe ki o maa ti awon ile epo to n ta epo ni owngogo pa.
O ni inira ti won n ko ara ilu si ti po ju.
Ajo Department of Petroleum Resources ti n ti irufe awon ile epo bee, sugbon fungba diedie ni won n se bee.
Tuface wa ni pe ekunrere iya lo ye ki won fi maa je won.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Tinubu kí wọn nílé Akala l’Ogbomọṣọ, ò tún sàbẹ̀wò sí Gómìnà Mákindé

Tinubu kí wọn nílé Akala l’Ogbomọṣọ, ò tún sàbẹ̀wò sí Gómìnà Mákindé Ọrẹ Òtítọ́jù Nítorí à…