Home iroyin Ìjọba ìpínlẹ̀ Èkó dẹ àwọn Ọ̀tẹlẹ̀múyẹ́ fún ìrẹsì
iroyin - December 23, 2017

Ìjọba ìpínlẹ̀ Èkó dẹ àwọn Ọ̀tẹlẹ̀múyẹ́ fún ìrẹsì

Gege bi ise gomina ipinle Eko, Akinwunmi Ambode lodoodun. O maa n ko iresi lopo yanturu wo ipinle Eko fun anfaani tolori-telemu. Iresi naa (Lake Rice) je eyi ti agbara gbogbo eniyan ka lati ra.
Iroyin wa kan si gomina pe awon alagbara kan ti n so iresi naa di okoowo. Ti won si n taa ni iye to ba wu won. Won ni awon oloselu kan le maa si soobu iresi fun iyawo won lasiko yii.
Eyi lo mu ki gomina Ambode de panpe kaakiri awon ibi ti iresi naa de si ni ipinle Eko. Gege bi oga ileese eto ogbin, Alagba Olayiwole Onansanya se jise gomina fun awon ara ilu lati fi won lokan bale. O ni ojo isinmi odun nikan ni awon eniyan ko ni ri iresi naa ra.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ìjàǹbá ọkọ̀ ní Fìdíwọ́ gbẹ̀mí èèyàn mẹ́fà láàrin ọ̀sẹ̀ kan

Ìjàǹbá ọkọ̀ ní Fìdíwọ́ gbẹ̀mí èèyàn mẹ́fà láàrin ọ̀sẹ̀ kan Ọrẹ Òtítọ́jù À fi kí Ọlọ́run má…