Home iroyin Bàbá Kérésì kú níbi tó ti ń f’ọ́mọ lẹ́bùn
iroyin - December 23, 2017

Bàbá Kérésì kú níbi tó ti ń f’ọ́mọ lẹ́bùn

Eni ti ko ba tii ku, ki o ma se fi eni to ku se yeye. Ko si eni ti ko ni ku, ko si eni ti oko baba re ko ni digboro. Ibi ti a maa ku si ati iru iku pelu asiko ti a maa ku ni Eledua o fi han enikankan.
Ayeye odun keresi to n lo lowo ni Orileede Italy, ni ibi ti baba keresi ti n fun awon akekoo lebun to n bo won lowo ni baba keresi ba dede subu lori ijokoo. Won sare du emi baba yii sugbon ki won to de ile iwosan, Elemii ti gbaa.
Ki Eledua ba wa te baba naa safefe rere.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Tinubu kí wọn nílé Akala l’Ogbomọṣọ, ò tún sàbẹ̀wò sí Gómìnà Mákindé

Tinubu kí wọn nílé Akala l’Ogbomọṣọ, ò tún sàbẹ̀wò sí Gómìnà Mákindé Ọrẹ Òtítọ́jù Nítorí à…