Home iroyin Àwọn Sẹ́nétọ̀ máa sàbẹ̀wò sí ọgbà Customs – Melaye
iroyin - December 23, 2017

Àwọn Sẹ́nétọ̀ máa sàbẹ̀wò sí ọgbà Customs – Melaye

Seneto Dino Melaye ati awon igbimo ti won gbe dide lori oro awon eso asobode ni won ti pinu lokan won pe awon maa titori awon ara ilu se abewo si gbogbo ogba awon eso asobode (Customs) yii ni asiko odun keresi ati odun tuntun yii.
Won ni o ye ki awon naa maa sinmi gege bii ti awon osise to ku, sugbon awon mo ibi ti bata ti n ta awon ara ilu lese ni o maa je ki awo se ise naa bii ise.
Won ni awon oja kan ti maa wa ni awon ogba won to ye ki won ti lu ta ni gbanjo ti owo die a tun fi wole si apo ijoba sugbon ti won ko lati se bee. Won ni awon miran wa to ye ki won ti dana sun ti ko dara fun jije tabi lilo omo eniyan ti won ko se bee. Won ni eyi lo maa je ki awon se abewo si gbogbo ogba ti won n ko nnkan si ni Naijiria.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Tinubu kí wọn nílé Akala l’Ogbomọṣọ, ò tún sàbẹ̀wò sí Gómìnà Mákindé

Tinubu kí wọn nílé Akala l’Ogbomọṣọ, ò tún sàbẹ̀wò sí Gómìnà Mákindé Ọrẹ Òtítọ́jù Nítorí à…