Home iroyin Rògbòdìyàn ẹgbẹ́ òsèlú PDP kò dé Ọ̀ṣun – Omisore
iroyin - December 22, 2017

Rògbòdìyàn ẹgbẹ́ òsèlú PDP kò dé Ọ̀ṣun – Omisore

Igbakeji gomina ni ipinle Osun tele, Oloye Iyiola Omisore ni ko si ohun to jo ede-aiyede ni ipinle Osun paapaa julo ninu egbe oselu PDP.
O ni eku n ke bi eku ni igba ti eye n ke bi eye ti omo eniyan naa si n fohun bi eniyan ninu egbe oselu PDP ti ipinle Osun.
Omisore ni oun maa dije du ipo gomina ni odun to n bo labe egbe oselu naa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

IPOB láwọn ò fẹ́ àbẹ̀wò Ààrẹ Buhari sí ìpínlẹ̀ Imo

IPOB láwọn ò fẹ́ àbẹ̀wò Ààrẹ Buhari sí ìpínlẹ̀ Imo Fẹ́mi Akínṣọlá Ọ̀fọ́n àn tọ̀ sí gbẹ̀gìr…