Home iroyin Owó náà ti pọ̀ jù fún ètò-àbò – Fayose
iroyin - December 20, 2017

Owó náà ti pọ̀ jù fún ètò-àbò – Fayose

Gomina ipinle Ekiti, Oloye Ayodele Fayose ni o ni oun ko le ri ko oun ma so. O ni owo Bilionu kan owo ile okeere naa ti po ju fun eto abo nikan. O ni ebi ti o wa ni ilu yii ju ki ijoba dede mu Bilionu kan owo ile okeere ti o ku aadota bilionu ki o wo irinwo bilionu naira (N370B).
Foyose ni koda ki o ma ju Bilionu meji naira lo, ki ijoba apapo pin-in fun ipinle kookan lori eto ilera, lori eto eko ati awon nnkan amaye-derun miran. O ni oun ko fara mo o rara ki ijoba apapo lo owo to po to bee lati fi daabo bo ilu.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ìjàǹbá ọkọ̀ ní Fìdíwọ́ gbẹ̀mí èèyàn mẹ́fà láàrin ọ̀sẹ̀ kan

Ìjàǹbá ọkọ̀ ní Fìdíwọ́ gbẹ̀mí èèyàn mẹ́fà láàrin ọ̀sẹ̀ kan Ọrẹ Òtítọ́jù À fi kí Ọlọ́run má…