Home Orisirisi Arẹ́gbẹ́ ń ṣe bẹbẹ l’Ọ́ṣun
Orisirisi - December 19, 2017

Arẹ́gbẹ́ ń ṣe bẹbẹ l’Ọ́ṣun

Gomina ipinle Osun, Ogbeni Rauf Aregbesola ni ko si bi ilu se le wu ki o le to, oun ko ni fi awon eniyan oun sile fun iya je. Eyi lo mu ki o tun se bi o se maa n se ni odoodun fun awon elesin Kirisiteeni ati Musulumi.
O ni Oko oju irin ofe tun ti wa lati ipinle Eko de ilu Osogbo ni ojo Satide, ojo ketalelogun osu yii. O ni oko naa maa gbera kuro ni Eko ni deede aago mewaa aaro fun anfaani awon omo ipinle Osun to ba fe lo se odun Keresi ni ilu won. O si tun se eto lati pada won naa ni ojo kerindinlogbon osu yii kan naa, ni eyi to n se ojo keji Keresi fun awon to ba fe pada si ipinle Eko. Bee si ni eto naa wa fun odun tuntun naa pelu irorun.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Tinubu kí wọn nílé Akala l’Ogbomọṣọ, ò tún sàbẹ̀wò sí Gómìnà Mákindé

Tinubu kí wọn nílé Akala l’Ogbomọṣọ, ò tún sàbẹ̀wò sí Gómìnà Mákindé Ọrẹ Òtítọ́jù Nítorí à…