Home iroyin Inú ẹgbẹ́ òsèlú APC náà ni mo sì wà – Saraki
iroyin - December 13, 2017

Inú ẹgbẹ́ òsèlú APC náà ni mo sì wà – Saraki

Aare ile igbimo asofin agba, Omowe Bukola Saraki ati olori ile igbimo asoju, Alagba Dogara pelu awon oloselu to loruko ninu egbe oselu APC ni won lo sabewo si Alagba Uche Secondus to jawe olubori gege bi alaga gbo-gbo-gbo fun egbe oselu PDP.
Abewo yii wa je ki awon kan maa gbee kiri pe Saraki ati awon kan to loruko ninu egbe oselu APC fe pada sinu egbe oselu PDP. Saraki ni ko si ohun to joo lowo bayii. O ni bi ilu se maa toro, ti awon ti ko n’ise maa r’ise, ti owon gogo gbogbo nnkan maa wale ni o koko je oun logun bayii, kii se kikuro ninu egbe kan bo si omiran.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Tinubu kí wọn nílé Akala l’Ogbomọṣọ, ò tún sàbẹ̀wò sí Gómìnà Mákindé

Tinubu kí wọn nílé Akala l’Ogbomọṣọ, ò tún sàbẹ̀wò sí Gómìnà Mákindé Ọrẹ Òtítọ́jù Nítorí à…