Home Orisirisi Ajimobi àti Olubadan ń gbéná wojú ara wọn
Orisirisi - December 12, 2017

Ajimobi àti Olubadan ń gbéná wojú ara wọn

Ọrọ ti a ro pe o ti ku regbé, ti o si tun ti ku regbè lo tun ti wu jade ni ana latari abajade ipade ti awon oloye agba Ibadan se.
Abajade ipade naa ni pe Olubadan gbodo tun ero re pa nipa aibowo fun alase tii se gomina ipinle Oyo, Alagba Abiola Ajimobi. Awon oloye naa ni ki Olubadan pe olorì re ko towo omo re baso, won ni ko lase lati maa kopa ninu ipade awon oloye agba Ibadan. Awon oloye agba to peju pese si ibi ipade naa ni. Oba Lekan Balogun, Otun Olubadan ti Ibadanland, Oba Owolabi Olakulehin; Balogun ti Ibadaland; Oba Abimbola Tajudeen Ajibola, Osi Balogun ti Ibadanland; Oba Eddy Oyewole, Ashipa Olubadan ti Ibadanland; Oba Lateef Gbadamosi Adebimpe, Ashipa Balogun ti Ibadanland; Oba Amidu Ajibade, Ekarun Olubadan ti Ibadanland ati Oba Kola Adegbola, Ekarun Balogun ti Ibadanland. Ojo mokanlelogun ni awon oloye naa fun Oba Saliu Adetunji tii se Olubadan ti Ibadan.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Tinubu kí wọn nílé Akala l’Ogbomọṣọ, ò tún sàbẹ̀wò sí Gómìnà Mákindé

Tinubu kí wọn nílé Akala l’Ogbomọṣọ, ò tún sàbẹ̀wò sí Gómìnà Mákindé Ọrẹ Òtítọ́jù Nítorí à…