Home iroyin Àdó olóró pa ènìyàn mẹ́tàlá ní Borno
iroyin - December 2, 2017

Àdó olóró pa ènìyàn mẹ́tàlá ní Borno

“Kaka ki ewe agbon de, pipele lo ma tun n pele sii”. Awon alakatakiti Boko Haram ni won tun de arabinrin meji ti won so ado iku mara lo si inu oja to wa ni ijoba ibile BIU ni ipinle Borno
Awon eniyan buruku yii see ni eni to ba ni kin ni a o se ni a n see fun. Ilu yii je ilu olori ogagun Buratai. Eniyan metala ni o ba isele naa lo ni igba ti eniyan merindinlogota si fara pa yanna-yanna.
Ki Eledua ba wa bu ororo itunu si okan awon ebi ti isele naa sele si.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ìjàǹbá ọkọ̀ ní Fìdíwọ́ gbẹ̀mí èèyàn mẹ́fà láàrin ọ̀sẹ̀ kan

Ìjàǹbá ọkọ̀ ní Fìdíwọ́ gbẹ̀mí èèyàn mẹ́fà láàrin ọ̀sẹ̀ kan Ọrẹ Òtítọ́jù À fi kí Ọlọ́run má…