Home Orisirisi Emi ati Ronaldo kii raaye ba ara wa soro – Messi
Orisirisi - November 28, 2017

Emi ati Ronaldo kii raaye ba ara wa soro – Messi

Agbaboolu aramonda, Lionel Messi, ti so pe oun ati Ronaldo ko le je ore timotimo tori awon kii ri aaye ba ara awon soro.

O ni awon kii sii rira deedee, bee bi eniyan meji kii ba rira deede, ti won kii si ri aaye ba ara won soro lemolemo, ko si bi won se fe je kori-kosun.

O ni lasiko ti awon ba fe gba awoodu olodoodun nikan ni awon maa n rira.

Sugbon sa o, o ni loooto, awon jo maa n fa ife eye mo ara won lowo ni, o ni awon kii se ota orun ko gbebo.

O ni awon oiroyin lo kan maa n wo oro naa gege bi eni pe ota ni oun ati Ronaldo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…