Home Orisirisi Tiwa Savage fi oyun pari ija laarin oun ati Teebilz  
Orisirisi - November 22, 2017

Tiwa Savage fi oyun pari ija laarin oun ati Teebilz  

Laipe yii, ikun akorin pataki, Tiwa Savage, yoo ta jade bii ti Funke Akindele.Idi ni pe oko re, ti gbogbo aye mo si Teebilz, ti gbin isu Olorun kan sibe – eyi ti ko see dowo bo.

Lai fa oro gun, obinrin naa tun ti loyun.

Odun 2015 lo bi akobi omo re.

Sugbon ija nla be sile laarin oun ati bale re, eyi ti won si ti dogbon pari.

Bi eni kan ba wa n siye meji lori boya ija naa ti pari tabi ko pari, ikun Tiwa Savage lo maa dahun eleyii.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…