Home Orisirisi Dugbedugbe n mi lori igbeyawo Dr Sid at Simi
Orisirisi - November 22, 2017

Dugbedugbe n mi lori igbeyawo Dr Sid at Simi

 

Okan awon ololufe akorin Dr Sid o bale lori kin lo n sele si igbeyawo re pelu Simi bayii.

Ohoun ti a n gbo ni pe igba n fi igbeyawo naa logbologbo.

Won ni nnkan ko dan moran mo, debi pe Simi ti maa n ko jade lawon igba kan.

Ohun to tun wa mu ki ifura yii po si nip e Dr Sid ati obinrin naa ko se ore mo lori ero alatagba Instagram, eyi to le tumo si pe ofon-on to si gbegiri, ki onikaluku ko eko re lowo.

Sugbon o adura wa ni pe ki Olorun fi alaafia si idile naa…

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…