Home iroyin Owo Fayose ba awon Fulani darandaran to jako ni Ijero
iroyin - November 20, 2017

Owo Fayose ba awon Fulani darandaran to jako ni Ijero

 

Sinkin ni nu Gomina Ipinle Ekiti, Ogbeni Ayodele Fayose, n dun bayii, latari bi owo awon olopaa ni ipinle naa se baa won Fulani darandaran kan ti won ni won da eran wo oko awon eniyan kan ni ilu Ijero Ekiti.

Won ni won ba gbogbo ohun ti won gbin sinu oko naa je.

Funra Fayose lo fi foto awon darandaran naa han, to sig be e sori ero alatagna Twitter re.

O wa ran gbogbo eniyan leti pe, ni Ipinle Ekiti, ese ni lati maa da eran ni ita gbangba, ati pe eni ti yoo ba sin maluu gbodo se ogba fun won.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…