Home Orisirisi Tinubu pada si Naijiria, o soro pataki ni Abuja
Orisirisi - November 16, 2017

Tinubu pada si Naijiria, o soro pataki ni Abuja

 

Gomina Ipinle Eko tele, Asiwaju Bola Tinubu, to tun je olori egbe APC, Asiwaju Bola Tinubu,  ti pada si Naijiria lati ilu oyinbo to lo leyin ti omo re, Jide Tinubu di oloogbe.

Tinubu ati iyawo re, Remi, pinnu lati yera die nitori opo ero to n wo lo ki i, to si tun fe lo tu iyawo ati omo oloogbe die.

O soro nibi iwe kan ti won fi lole nilu Abuja, eyi to so nipa awon aseyori ijoba Aare Muhammadu Buhari.

O so nipa bi Buhari ti segun ogun Boko Haram ati aseyori re lori eto ogbin ati oro aja lapapo.

Aare Buhari naa wa nibi eto naa, nibi ti opo ti patewo nla fun Tinubu.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…