Home Orisirisi Ko dara bi Buhari ko se ki mi ku oriire ojo ibi mi – Fayose
Orisirisi - November 15, 2017

Ko dara bi Buhari ko se ki mi ku oriire ojo ibi mi – Fayose

Yoruba bo won ni afeni-i-pe-lokose, gbogbo ise to ba ri nii be ni. Abi bee ni oro to wa laarin Gomina Ayodele Fayose ati Aare Muhammadu Buhari ni?

Boya owe to si dara lati lo ni pe ‘Bi a ba n ja, bii ka ku ko’; ati pe ‘Bi a ko ba gbagbe oro ana, a ko nii ri eni kana a ba sere’.

Eyi lo difa fun Gomina Fayose to so fun awon oniroyin lonii pe ohun kan ti ko ba mu inu oun du pupo lonii ni bi Aare Buhari ba ki oun ku oriire ojo ibi aadota odun ti oun se lonii.

O ni o ye ki Buhari pe oun ni idaji oni, ki o ki oun ku oriire, sugbon ko se bee.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…