Home iroyin Pípadà Sẹ́nátọ̀ Ndume dá àríyànjiyàn sílẹ̀
iroyin - November 14, 2017

Pípadà Sẹ́nátọ̀ Ndume dá àríyànjiyàn sílẹ̀

Seneto Alli Ndume ni ede aiyede wa laarin re ati olori ile igbimo asofin agba, Bukola Saraki ni nnkan bii osu mejo seyin. Won pe ijokoo alabe-sekele lori oro naa, abajade awon igbimo naa ni pe ki Ndume lo roo kun nile fun igba die.

Oro yii di oro ile ejo, “wa loni, wa lola lo kuku maa n mu ki ejo su ni”. Lati osu kejo naa ni idajo kan waye ni ile-ejo giga kan to fi ikale si Abuja. Adajo agba, Babatunde Quadri lo se idajo naa ni ilu Abuja. O ni awon Seneto ko letoo lati ja iwe gbele re fun Seneto Ndume. Eyi lo mu ki idajo naa pe Ndume pada senu ise kiakia.

Mike Ozekhome (SAN) ti lo pejo ko-temi-lorun, eyi lo wa fa ariyanjiyan laarin awon Seneto. Awon kan ni awon ko nilo ejo pipe mo, ki won je ki awon fi owo ile too. Awon kan ni ki ejo maa te siwaju.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…