Home Orisirisi Mo ma n mu igbo ati codeine tele – Toyin Aimakhu
Orisirisi - November 14, 2017

Mo ma n mu igbo ati codeine tele – Toyin Aimakhu

 

Osere fiimu ti a mo si Toyin Aimakhu ti jewo pe titi di odun to koja, o fee ma si oogun oloro ti oun kii lo.

Arabinrin naa ti o ti yi oruko  ara re pada si Toyin Abraham salaye pe ninu ile oun ati laarin awon ore oun, bi awon se n lo codeine ni awon n mu imukumu.

Sugbon o salaye pe Olorun ti gbakoso bayii, ti oun si ti fi gbogbo re sile pata.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…