Home ERÉ ÌDÁRAYÁ Olomoge kan salaye bi Ronaldo se ba oun sun
ERÉ ÌDÁRAYÁ - November 12, 2017

Olomoge kan salaye bi Ronaldo se ba oun sun

 

 

Olomobinrin lenje-lenje kan, Natacha Rodrigues, ti so pe agbaboolu ara, Christiano Ronaldo, gbe oun sun ni ojo kan leyin ti awon mejeeji subu ninu ife.

Bi o tile je pe Ronaldo ko tii se igbeyawo ege bii ti Messi, o ni obinrin to ti bimo fun un.

Natacha ni ori ero alatagba ni awon ti koko maa n soro ife si ara awon, ti ara awon mejeeji ko fi gba a mo.

A ko tii mo ohun ti Ronaldo ati obinrin re yoo se lori oro yii.

O ni oodunrun owo Euro (300 euros) ni Ronaldo fun oun ki oun fi wo tasin nigba ti awon sere oge tan.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…