Home Orisirisi Idi ti n ko fi tete se igbeyawo – Afeez Oyetoro
Orisirisi - November 12, 2017

Idi ti n ko fi tete se igbeyawo – Afeez Oyetoro

 

Gbajugbaja osere alawada, Afeez Oyetoro, ti opo eniyan mo si Saka, ti so pe oun ti to mo ogoji odun ki oun to se igbeyawo.

O se alaye pe lasiko naa, a ri lara awon ore oun to ti n se igbeyawo fun omo to ti bi.

Saka so pe okan oun ko tete lo sibi igbeyawo, tori ise akada ati ere tiata ni oun gbaju mo.

Ni Pataki, o ni aitete rikan-sekan, aini ati iponju ni ko je ki oun ni igboya lati feyawo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…