Home Orisirisi Haba! Fanikayode fi Amaechi we aja digbolugi!
Orisirisi - November 12, 2017

Haba! Fanikayode fi Amaechi we aja digbolugi!

 

Minisita fun Oro  Oko Ofurufu tele, Oloye Femi Fani-Kayode, tun ti ju bombu oro nla kan, nigba to pe Minisita fun Oro Irinna bayii, Ogbeni Rotimi Amaechi, ni aja digbolugi.

O so eyi nigba to n soro lori rogbodiyan kan to sele lojo Satide laarin awon alaabo Amaechi pelu ti Gomina Ipinle Rivers, Ogbeni Nyeson Wike.

Loju ti Fani-Kayode, Amaechi lo jebi. O wa ro Aare Buhari pe ki o mu aja re so.

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…