Home Orisirisi Anfaani wa ninu ki eniyan maa sanwo idamewaa – D’Banj
Orisirisi - November 12, 2017

Anfaani wa ninu ki eniyan maa sanwo idamewaa – D’Banj

 

Akorin hip hop ti a mo si D’Banj ti so erongba re lori awuyewuye to n lo lowo lori owo idamewaa ni soosi.

Won eniyan kan ti n so lenu ojo meta yii pe ko ye ki awon olori ijo Kirisiti maa gba owo idamewaa.

Won ni Bibeli ko pon on ni dandan fun enikeni lati se bee.

Lara won ni soro-soro ori redio kan ti a mo si Daddy Freeze.

Koda, nigba ti Olori Agba fun Ijo Redeemed Christtian Church of God, Pasito E. A. Adeboye so pe dandan ni owo idamewaa.

Lojo Sunday, D’Banj naa wad a si oro naa.

O so pe ohun to lere pupo ni lati maa san owo naa.

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…