Home Orisirisi  2019: Jonathan gba Atiku nimoran lori Obasanjo
Orisirisi - November 12, 2017

 2019: Jonathan gba Atiku nimoran lori Obasanjo

Aare Orile-ede yii tele, Dokita Goodluck Jonathan, ti gba Alhaji Atiku Abubakar nimoran pe o ni lati fi ti Oloye Olusegun Obasanjo se to ba fe du ipo aare ni 2019.

Atiku ni igbakeji Obasanjo ki nnkan to daru laarin won nigba ti Obasanjo je Aare.

Obasanjo naa lo je baba-nigbejo Jonathan tele, ki ija to be sile laarin won, ti Jonathan si koyin si i. Sugbon abo eleyi ko dara fun Jonathan,tori awon APC gba ijoba mo o lowo ni 2019.

Nigba ti o wa n gba Atku nimoran lori lori erongba re lati di Aare, Jonathan ni eni ti Obasanjo ko ba fi ti Obasanjo se, to ba fe di Aare, boya ni o le rowo mu.

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…