Home Orisirisi Tuface ni ki Eedris Abdukareem gbenu soun-un
Orisirisi - November 9, 2017

Tuface ni ki Eedris Abdukareem gbenu soun-un

Akorin pataki, Tuface Idibia, ti ni ki akorin raapu, Idris Abdukareem, ati okunrin kan ti oun ati Tuface jo wa ninu egbe akorin Plantazion Boys tele, Blackface, gbe enu won soun-oun.

O ni ki won gbenu lowo ki won ye so isokuso nipa orin oun.

O ni oun gbo nigba ti won n so pe orin oun kii jinle, ti won si tun so pe ikokuko lo poju ninu orin awon akorin Naijiria.

O ni bi awon mejeeji ba mo orin ko, ti orin won da won loju, ki won maa ko orin naa fun araye gbo, dipo ti won yoo fi maa bu elomiran.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…