Home Orisirisi Funke Akindele koja lo si London lati lo bimo
Orisirisi - November 9, 2017

Funke Akindele koja lo si London lati lo bimo

 

Gbogbo eyin ololufe osere atata ti a mo si Funke Akindele, e ku ireti ayo o. Eru yoo so layo; a maa gbohun iya, a maa gbohun omo. Laipe, ibeji lanti-lanti ni o. Boya okunrin meji lanti-lanti, boya okunrin kan ati obinrin kan, boya obinrin arewa si ni awon mejeeji yoo je.

Eredi adura yii ni pe Funke ti lo si ilu London bayii, a si gbo pe ibe ni yoo wa titi yoo fi bimo.

Pelu ogo Olorun, ibeji ni oun ati oko re n reti. Pelu idunnu ni o se taari ikun siwaju ni Airport, ti opo eniyan si n ki i ni mesan-an mewaa.

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…