Home iroyin A máa da Bíríìjì Jibowu àti Ojuelegba wó – Rotimi Amaechi
iroyin - November 7, 2017

A máa da Bíríìjì Jibowu àti Ojuelegba wó – Rotimi Amaechi

Minisita fun eto igboke-gbodo oko, Rotimi Amaechi lo n ba awon oniroyin soro nipa opopona oju irin ti ijoba apapo fe ko si Eko si Ibadan.

O ni ohun to n daa duro naa ni eto aabo to gbopan ti awon fe seto fun awon alawo funfun to maa sise naa.

O ni gbogbo eto lo ti to tan, nitori pe oga patapata fun awon olopaa ti mo nipa re. I G ati awon eleto aabo ilu si ti se ileri lati daabo bo awon alawo funfun naa ki ise won le tete pari.

Minisita tun ni ijoba maa da Biriiji Jibowu ati Ojuelegba to wa ni ipinle Eko wo, awon wa maa tun un ko ti o si maa ga daadaa, ki o le baa fi aaye gba oko oju irin lati koja.

Ijoba apapo ni eyi tun maa din ijamba oju popo ku nitori pe akoba kekere ko ni awon oko ajagbe n da si awon ona wa gbogbo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…