Home iroyin Ìgbà ìkórè Nàìjíríà ti dé tán – Lai Mohammed
iroyin - November 6, 2017

Ìgbà ìkórè Nàìjíríà ti dé tán – Lai Mohammed

Minisita fun iroyin ati asa ni orileede Naijiria lo fi gbogbo aye lokan bale ni ojo satide ni ilu Eko, nigba ti o n soro nibi ipate oja to waye. O ni gbogbo awa ti a jo farada owon gbogbo nnkan ti awon ijoba ana ko wa si naa ni a jo maa je oro re laipe yii.

O ni gbogbo eto lo ti to tan, igbadun lo ku fun awon omo orileede yii nitori pe a ti la ewu koja.

Aare tele ri ni orileede yii, Oloye Olusegun Obasanjo naa kin oro minisita leyin pe gbogbo igbese ijoba ode-oni lo tumo sii pe ilu yii si maa tun dara pada.

Obasanjo ni ijoba Buhari gbaju mo okoowo bi awon ileese se maa gberu ati bi awon olokoowo miran se maa wa da ise sile ni ilu yii.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…