Home iroyin Ẹ̀mí kò láàrọ̀!
iroyin - November 6, 2017

Ẹ̀mí kò láàrọ̀!

Gbogbo ohun ti o wu ki o sẹlẹ loju titi mọrosẹ, ẹ jẹ ki a wa ibomiran lati lọ maa pari rẹ. Isẹlẹ inu fidio yii bayan ni inu jẹ. Ẹ wo ikọlu kekere ti ko fọ ina mọto kankan, ẹ wa wo iye ẹmi to ba iru isẹlẹ naa lọ.

Ẹ jẹ ki a maa sọra, gbogbo ẹya ara mọto lo see paarọ sugbon ẹmi ko laarọ!

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…