Home Orisirisi Kin lo n sele si igbeyawo Femi Adebayo?
Orisirisi - November 4, 2017

Kin lo n sele si igbeyawo Femi Adebayo?

Ibeere yii ni awon eniyan to sun mo osere fiimu, Femi Adebayo, n beere pelu ijaya bayii.
Laipe yii ni Femi n ki obinrin naa, Omotayo, ni mesan-an, mewaa, to si n so pe ife to n joba laarin awon kii se keremi.
Omotayo ni obinrin keji ti Femi maa fe, leyin ti igbeyawo re akoko fori sanpon.
Ohun ti o wad a ijaya sile bayii nip e won ni Femi ati Omotayo ti yo foto igbeyawo won kuro lori ate Instagram, ti won ko si jo sore lori ero alatagba naa mo – eyi ti awon oloyinbo n pe ni unfollow.
Femi Adebayo ti so pe ko si ija laarin oun ati iyawo oun. Adura wa naa nip e ki alaafia job anile tiwon ati tiwa naa..

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Tinubu kí wọn nílé Akala l’Ogbomọṣọ, ò tún sàbẹ̀wò sí Gómìnà Mákindé

Tinubu kí wọn nílé Akala l’Ogbomọṣọ, ò tún sàbẹ̀wò sí Gómìnà Mákindé Ọrẹ Òtítọ́jù Nítorí à…