Home Orisirisi Kii se emi ni Ooni Ogunwusi fe fi se olori – Ara
Orisirisi - November 4, 2017

Kii se emi ni Ooni Ogunwusi fe fi se olori – Ara


Obinrin onilu kasiara, Araola Olumuyiwa, to n je Ara ni kukuru, ti se alaye pe ohun ti awon eniyan kan n so pe o n sele laarin oun ati Ooni ti Ife, Oba Adeyeye Ogunwusi, ko ri bee.
Lati igba ti Ara ti n lo si aafin Ooni lore-koore ni awon kan ti n so pe o jo pe nnkan kan sa pamo sibe.
O le debi pea won kan n pe Ara ni Olori.
Oro naa wa ni itumo to jinle nigba ti Olori Ooni tele, iyen Wuraola Zynab, ko kuro laafin, nigba ti igbeyawo naa fori sanpon.
Ninu eyi naa ni Ooni tun fi Ara je oye Asoju Asa (Cultural Ambassador. O wa jo gate, ko jo gate, o fese mejeeji tiro.
Sugbon Ara ti so pe loooto ni oun sunmo aafin pekipeki, sugbon ko si oro ife laarin oun ati Oba Ogunwusi.
O ni otito si nip e oun naa n se ipalemo lati dara po mo okunrin miiran, sugbon Ooni ko ni ololufe oun..

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Tinubu kí wọn nílé Akala l’Ogbomọṣọ, ò tún sàbẹ̀wò sí Gómìnà Mákindé

Tinubu kí wọn nílé Akala l’Ogbomọṣọ, ò tún sàbẹ̀wò sí Gómìnà Mákindé Ọrẹ Òtítọ́jù Nítorí à…