Home Orisirisi Awon ti won ni mo ja Damola Olatunji gba mo obinrin miiran lowo ko mo hulehule oro – Arugba
Orisirisi - November 4, 2017

Awon ti won ni mo ja Damola Olatunji gba mo obinrin miiran lowo ko mo hulehule oro – Arugba

Osere fiimu ti a mo si Bukola Awoyemi, ti opo eniyan mo si Arugba, ti so pea won ti won ni oun ja Damola Olatunji gba mo eni to ko fe lowo ko mo idi oro ni.
O ni ti won ba mo bi oro se lo, won ko ni wi ohun ti won n wi.
Arugba ko so hulehule oro, sugbon o ni oro naa ka oun lara nigba naa.
O ni o ba oun lokan je gidi, sugbon gbogbo eyi ti ditan bayii.
Ibeji lanti-lanti ni Bukola bi fun Damola, to si je pe ayo ati alaafia ni awon mejeeji fi n saye.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Tinubu kí wọn nílé Akala l’Ogbomọṣọ, ò tún sàbẹ̀wò sí Gómìnà Mákindé

Tinubu kí wọn nílé Akala l’Ogbomọṣọ, ò tún sàbẹ̀wò sí Gómìnà Mákindé Ọrẹ Òtítọ́jù Nítorí à…