Home iroyin Adiitu Eledumare: Omo ile-iwe bi ibeta!
iroyin - November 4, 2017

Adiitu Eledumare: Omo ile-iwe bi ibeta!

Nigba ti onkowe ara, D. O. Fagunwa, n ko nipa ‘Aditu Oliodumare’, o ri pupo ko to se bee. Ohun kan ti ko ri to fi ku ni isele agbayanu kan to sese sele ni Naijiria.
Omo ile-eiwe Abia State College of Health, Science and Management Technology, Aba, Felicia Ifeanyi, lo bi ibeta lojo Jimoo.
Ohun to tun se Pataki nip e bale re, to n je Okechukwu, ko nise lowo.
Felicia ni oun ko mo pe ibeta lo n bo lona, sugbon oun ati oko re gbagbo pe Olorun yoo duro ti awon lori itoju awon omo naa.
Amin o.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ìjàǹbá ọkọ̀ ní Fìdíwọ́ gbẹ̀mí èèyàn mẹ́fà láàrin ọ̀sẹ̀ kan

Ìjàǹbá ọkọ̀ ní Fìdíwọ́ gbẹ̀mí èèyàn mẹ́fà láàrin ọ̀sẹ̀ kan Ọrẹ Òtítọ́jù À fi kí Ọlọ́run má…