Home iroyin Kò síjà láàrin èmi àti Buhari – Tinubu
iroyin - October 30, 2017

Kò síjà láàrin èmi àti Buhari – Tinubu

Nigba ti Asiwaju Bola Tinubu jade nibi ipade bonkele to se pelu Aare Buhari ni awon oniroyin bere si ni fi oro wa lenu wo. Won ni o dabi eni pe gbolohun-aso wa laarin oun ati Buhari.

Tinubu ni ko si ohun to jọ gbolohun-aso rara. O ni gbogbo eniyan lo mo pe oun ko le ri ki oun dake. O ni ti ija ba wa, gbogbo aye lo ti maa mo, koda ti isejoba re ko ba te oun lorun, oun ko ba ti lahun sita nitori pe, a kii pa ohun mo agogo lenu.

Tinubu ni oun ko le salaye gbogbo ohun ti awon so ni ipade naa bayii, ni eyi to mu ko kuro ni odo awon oniroyin naa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…