Home iroyin Buhari ṣe ìpàdé pàjáwìrì pẹ́lú Tinubu àti àwọn àgbà ẹgbẹ́ APC
iroyin - October 30, 2017

Buhari ṣe ìpàdé pàjáwìrì pẹ́lú Tinubu àti àwọn àgbà ẹgbẹ́ APC

Aare orileede yii, Muhammadu Buhari se ipade pajawiri pelu Asiwaju Bola Tinubu ni idakọnkọ, ki o to tun wa se omiran pelu Aare ile igbimọ asofin agba, Bukola Saraki, olori ile igbimo asoju, Yakubu Dogara, alaga awọn gomina egbe oselu APC to tun je gomina ipinlẹ Zamfara, Abdullaziz Yari ati John Odigie-Oyegun to jẹ alagba ẹgbẹ oselu APC.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…